Ìròyìn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Abia, Alex Otti, ti sọ pé ìjọba alágbádé (democracy) kò kùnà ní Nàìjíríà, bí kò ṣe pé àwọn olóṣèlú àti araàlú ló ti kùnà láti ṣiṣẹ́ rẹ̀ dáadáa.
Ìròyìn Ẹgbẹ́ PDP ti Wike Tun Yan Abdulrahman Mohammed ati Sam Anyanwu Gẹ́gẹ́ Bí Alága àti Akọ̀wé Gbogbogbo