Ìròyìn Gómìnà Ìpínlẹ̀ Abia, Alex Otti, ti sọ pé ìjọba alágbádé (democracy) kò kùnà ní Nàìjíríà, bí kò ṣe pé àwọn olóṣèlú àti araàlú ló ti kùnà láti ṣiṣẹ́ rẹ̀ dáadáa.